Aare Jonathan sope kosi ilu kankan to bosi owo boko haram lati ose kan seyin.
Friday, 21 November 2014
Ijakadi Nitori Ipolongo Ajimobi Nilubadan
Oro di eniti Olohun koyo odile nilu Ibadan lojo eti ti se Friday lagbo oke Ado nigbati awon omo isotan da igboro ru latari pe Gomina Ajimobi fe lati wa polongo ibo fun saa keji. Awon i isele naa sojuwon sope opolopo lo farapa nigbati wahala naa bere.
Awon Olopa Gbajoba Ile Asofin Apapo
Wahala to be sile laarin ile asofin apapo pelu ijoba gbona ara yo lana ode yii bi awon olopa se gba akoso ile asofin naa peluu yiyin ibon taju-taju lati le awon asofin si igbo. Nse ni a ri gbo pe awon olopa naa soro pelu bi won se sope won yinbon taju-taju naa lu abenugan ile asofin kekere, Aminu Tambuwa.