Awon Olopa Gbajoba Ile Asofin Apapo
Wahala to be sile laarin ile asofin apapo pelu ijoba gbona ara yo lana ode yii bi awon olopa se gba akoso ile asofin naa peluu yiyin ibon taju-taju lati le awon asofin si igbo. Nse ni a ri gbo pe awon olopa naa soro pelu bi won se sope won yinbon taju-taju naa lu abenugan ile asofin kekere, Aminu Tambuwa.
0 comments:
Post a Comment